Skip to content
Commit
Permalink
Translated using Weblate (Yoruba)
Browse files Browse the repository at this point in the history
Currently translated at 99.6% (254 of 255 strings)
Translation: SecureDrop/SecureDrop
Translate-URL: https://weblate.securedrop.org/projects/securedrop/securedrop/yo/
• Loading branch information
OmoYooba authored and Weblate committed Sep 25, 2019
1 parent a8b78b7 commit 570f297
Showing 1 changed file with 85 additions and 23 deletions.
108 changes: 85 additions & 23 deletions securedrop/translations/yo/LC_MESSAGES/messages.po
Original file line number Diff line number Diff line change
Expand Up @@ -7,7 +7,7 @@ msgid ""
msgstr ""
"Project-Id-Version: SecureDrop 1.0.0~rc1\n"
"Report-Msgid-Bugs-To: [email protected]\n"
"PO-Revision-Date: 2019-09-24 13:39+0000\n"
"PO-Revision-Date: 2019-09-25 15:39+0000\n"
"Last-Translator: Adéṣínà Ayẹni <[email protected]>\n"
"Language-Team: Yoruba <https://weblate.securedrop.org/projects/securedrop/"
"securedrop/yo/>\n"
Expand Down Expand Up @@ -1091,31 +1091,38 @@ msgid ""
"the onion button in the Tor browser's toolbar to clear all history of "
"your SecureDrop usage from this device."
msgstr ""
"O ṣeun tí o jáde kúrò ní sáà rẹ! Jọ̀wọ́ yan \"Ìdánimọ̀ Tuntun\" nínúu bọ́"
"tììnì àlùbọ́sà lóríi pátákòirinṣẹ́ aṣàwáríkiri Tor láti pa gbogbo àkọsílẹ̀ "
"rẹ bí o ṣe lo SecureDrop lórí ẹ̀rọ yìí rẹ́."
#: source_templates/lookup.html:10
msgid "Sorry we haven't responded yet!"
msgstr ""
msgstr "Máà bínú a ò tíì fèsì!"
#: source_templates/lookup.html:11
msgid ""
"Our SecureDrop recently experienced a surge of activity. For security "
"reasons, the creation of a two-way communication channel was delayed "
"until you checked in again."
msgstr ""
"SecureDrop wa rí ìrúsókèe lílò láì pẹ́ yìí. Fún aabo tí ó yanrantí, a ṣe "
"ìdádúró sí ìfẹ̀rílàdí ọlọ́nà-méjì kan títí tí o ó fi padà wá."
#: source_templates/lookup.html:12
msgid ""
"Please rest assured that we were able to download your submission, and "
"check back again later for a reply."
msgstr ""
"Jọ̀wọ́ a fi dá ọ lójú wípé a lè ṣe-àgbàálẹ̀ ìfisílẹ̀ rẹ, kí o padà wá fún "
"èsì."
#: source_templates/lookup.html:18
msgid "Submit Files or Messages"
msgstr ""
msgstr "Ṣe-àfisílẹ̀ Fáìlì tàbí Iṣẹ́-ìjẹ́"
#: source_templates/lookup.html:19
msgid "You can submit any kind of file, a message, or both."
msgstr ""
msgstr "O leè Ṣe-àfisílẹ̀ onírúurú fáìlì, iṣẹ́-ìjẹ́, tàbí méjèèjì."
#: source_templates/lookup.html:21
msgid ""
Expand All @@ -1124,22 +1131,26 @@ msgid ""
"key before submission. Files are encrypted as they are received by "
"SecureDrop."
msgstr ""
"Bí o bá mọ bí a ṣe ń lo GPG, o lè yí-odù fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ẹ̀ rẹ padà sí "
"wa kí o tó ṣe-àfisílẹ̀. Odù fáìlì ń yí padà sí ti ààbò bí SecureDrop ṣe "
"ń gbà á."
#: source_templates/lookup.html:22
msgstr ""
#: source_templates/lookup.html:32
msgid "Maximum upload size: 500 MB"
msgstr ""
#: source_templates/lookup.html:35
msgid "Write a message."
msgstr ""
msgstr "Kọ iṣẹ́-ìjẹ́ kan."
#: source_templates/lookup.html:57
msgid "Read Replies"
msgstr ""
msgstr "Ka àwọn Èsì"
#: source_templates/lookup.html:62
msgid ""
Expand All @@ -1148,50 +1159,53 @@ msgid ""
" with them. This also lets us know that you are aware of our reply. You "
"can respond by submitting new files and messages above."
msgstr ""
"O ti ní èsì kan. Láti dáàbò bo ìdánimọ̀ rẹ bí ẹnìkan bá jí orúkọ-odù rẹ, "
"jọ̀wọ́ pa gbogbo èsì rẹ́ bí o bá bùṣe pẹ̀lúu wọn. Èyí tún mú wa mọ̀ wípé o "
"mọ̀ sí èsìi wa. O lè fèsì nípa fífi fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ tuntun sílẹ̀ sókè."
#: source_templates/lookup.html:76
msgid "Delete this reply?"
msgstr ""
msgstr "Pa èsì yìí rẹ́?"
#: source_templates/lookup.html:87
msgid "DELETE ALL REPLIES"
msgstr ""
msgstr "PA GBOGBO ÈSÌ RẸ́"
#: source_templates/lookup.html:90
msgid "Are you finished with the replies?"
msgstr ""
msgstr "Ṣé o ti parí pẹ̀lú àwọn èsì náà?"
#: source_templates/lookup.html:91
msgid "YES, DELETE ALL REPLIES"
msgstr ""
msgstr "BẸ́Ẹ̀NI, PA GBOGBO ÈSÌ RẸ́"
#: source_templates/lookup.html:92
msgid "NO, NOT YET"
msgstr ""
msgstr "RÁRÁ, KÒÌ YÁ"
#: source_templates/lookup.html:96
msgid "There are no replies at this time."
msgstr ""
msgstr "Kò sí èsì kankan ní àsìkò yìí."
#: source_templates/lookup.html:105
msgid "Remember, your codename is:"
msgstr ""
msgstr "Rántí, orúkọ-odù rẹ ni:"
#: source_templates/lookup.html:106
msgid "Show"
msgstr ""
msgstr "Ṣ'àfihàn"
#: source_templates/lookup.html:108
msgid "Hide"
msgstr ""
msgstr "Fi-pamọ́"
#: source_templates/notfound.html:3
msgid "Page not found"
msgstr ""
msgstr "Ojú-ìwé ò jẹ́ rírí"
#: source_templates/notfound.html:5
msgid "Sorry, we couldn't locate what you requested."
msgstr ""
msgstr "Ó dun'ni, a kò leè rí ohun tí o béèrè fún."
#: source_templates/session_timeout.html:6
msgid ""
Expand All @@ -1201,50 +1215,67 @@ msgid ""
"SecureDrop usage from this device. If you are not using Tor Browser, "
"restart your browser."
msgstr ""
"Àsìkò sáà rẹ ti tán nítorí pé o kò ṣe nǹkan kan. Jọ̀wọ́ fàṣẹwọlé lẹ́ẹ̀kan sí "
"i bí o bá fẹ́ tẹ̀síwájú pẹ̀lú SecureDrop, tàbí kí o yan \"Ìdánimọ̀ Tuntun\" "
"láti inúu bọ́tììnì àlùbọ́sà lóríi pátákòirinṣẹ́ aṣàwáríkiri Tor láti pa "
"gbogbo àkọsílẹ̀ oríi SecureDrop rẹ́ ní orí ẹ̀rọ yìí. Bí o kò bá lo "
"Aṣàwáríkiri Tor, tún aṣàwáríkiriì rẹ bẹ̀rẹ̀."
#: source_templates/tor2web-warning.html:3
msgid "Why is there a warning about Tor2Web?"
msgstr ""
msgstr "Èé ṣe tí ìkìlọ̀ ṣe wà nípa Tor2Web?"
#: source_templates/tor2web-warning.html:4
msgid "Using Tor2Web to connect to SecureDrop will not protect your anonymity."
msgstr ""
"Lílo Tor2Web láti ṣe-ìṣàsopọ̀ sí SecureDrop kò ní fi ààbò bo àìlórúkọọ̀ rẹ."
#: source_templates/tor2web-warning.html:5
msgid ""
"It could be possible for anyone monitoring your Internet traffic (your "
"government, your Internet provider), to identify you."
msgstr ""
"Ó ṣe é ṣe fún ẹnikẹ́ni láti máa ṣọ́ bí o ti ṣe ń lo Ayélujára (ìjọbaà rẹ, "
"apèsè Ayélujáraà rẹ), láti dá ọ mọ̀."
#: source_templates/tor2web-warning.html:6
msgid ""
"instead."
msgstr ""
"A <lágbára>fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ rọ̀ ọ́ </lágbára> kí o kúkú lo \n"
"náà."
#: source_templates/use-tor-browser.html:3
msgid "You Should Use Tor Browser"
msgstr ""
msgstr "Ó Yẹ Kí O Lo Aṣàwáríkiri Tor"
#: source_templates/use-tor-browser.html:4
msgid ""
"If you are not using Tor Browser, you may not be "
"anonymous."
msgstr ""
"Bí o kò bá lo Aṣàwáríkiri Tor, o lè máà wà ní ipò àìlórúkọ</lágbára>."
#: source_templates/use-tor-browser.html:5
msgid ""
"If you want to submit information to SecureDrop, we strongly "
"advise you to install Tor Browser and use it to access our site "
"safely and anonymously."
msgstr ""
"Bí o bá fẹ́ ṣe-àfisílẹ̀ ìwífún sí oríi SecureDrop, a <lágbára>rọ̀ "
"ọ́</lágbára> kí o fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ, kí o sì lò ó láti fi "
"wọ inú ibùdóo wa pẹ̀lú ààbò àti ìpamọ́ ipò àìlórúkọ."
#: source_templates/use-tor-browser.html:6
msgid ""
"Copy and paste the following address into your browser and follow the "
"instructions to download and install Tor Browser:"
msgstr ""
"Gbé ẹ̀dà ojúlé lẹ́sẹẹsẹ sórí aṣàwáríkiriì rẹ, kí o sì tẹ̀lé ìtọ́nà náà láti "
"gbà á sílẹ̀ àti fi Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ:"
#: source_templates/use-tor-browser.html:9
msgid ""
Expand All @@ -1253,50 +1284,68 @@ msgid ""
[email protected]
and a bot will answer with "
"instructions."
msgstr ""
"Bí gbígba Aṣàwáríkiri Tor sí orí ẹ̀rọọ̀ rẹ bá mú ìfura dání àti pé kò sí "
"àrídájú wípé apèsè ìfìwéránṣẹ́ (ímeèlì) rẹ wà ní abẹ́ ìṣọ́, o lè kọ̀wé "
"sí
[email protected]
, tí ẹ̀rọ yóò sì dáhùn pẹ̀lú ìtọ́nà ohun "
"tí o ó ṣe."
#: source_templates/why-journalist-key.html:3
msgid "Why download the journalist's public key?"
msgstr ""
"Kí ló dé tí ó fi yẹ kí akọ̀ròyìn ó gba kọ́kọ́rọ́ọ gbogboògbò sílẹ̀ sórí ẹ̀rọ?"
#: source_templates/why-journalist-key.html:4
msgid ""
"SecureDrop encrypts files and messages after they are submitted. "
"Encrypting messages and files before submission can provide an extra "
"layer of security before your data reaches the SecureDrop server."
msgstr ""
"SecureDrop máa ń yí odù fáìlì àti iṣẹ́-ìjẹ́ padà fún ààbò ní kété tí o bá ti "
"ṣe-àfisílẹ̀. Yíyí iṣẹ́-ìjẹ́ àti fáìlì padà-sì-odù-ààbò kí o tó ó ṣe-àfisílẹ̀ "
"leè pèsè àlékún ìpele ààbò kí dátà rẹ ó dé apèsè SecureDrop náà."
#: source_templates/why-journalist-key.html:5
msgid ""
"If you are already familiar with the GPG encryption software, you may "
"wish to encrypt your submissions yourself. To do so:"
msgstr ""
"Bí o bá mọ iṣẹ́-àrídìmú ìyí-data-padà-sí-odù-fún-ààbò GPG, ó lè hùn ọ́ kí o "
"yí odù àfisílẹ̀ rẹ padà fún ààbò fúnraà rẹ. Láti ṣe bẹ́ẹ̀:"
#: source_templates/why-journalist-key.html:7
msgid ""
"file with the extension .asc"
msgstr ""
"ni kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò pẹ̀lú <odù>.asc</odù>"
#: source_templates/why-journalist-key.html:8
msgid "Import it into your GPG keyring."
msgstr ""
msgstr "Kó o wọlé sínúu GPG rẹ pẹ̀lú òrùkakọ́kọ́rọ́."
#: source_templates/why-journalist-key.html:10
msgid ""
".asc file you just downloaded and it will be automatically "
"imported to your keyring."
msgstr ""
"ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣàgbàsílẹ̀ẹ rẹ̀ lẹ́ẹ̀-mejì yóò sì di kíkó wọlé sí òrùkakọ́kọ́rọ́ọ̀ rẹ "
"fúnra rẹ̀."
#: source_templates/why-journalist-key.html:11
msgid ""
"If you are using Mac/Linux, open the terminal. You can import the key "
"with gpg --import /path/to/key.asc."
msgstr ""
"Bí o bá ń lo Mac/Linux, ṣí terminal. O leè kó kọ́kọ́rọ́ wọlé pẹ̀lú <odù>gpg "
"--\n"
"kówọlé/ipaọ̀nà/sí/kọ́kọ́rọ́.asc</odù>."
#: source_templates/why-journalist-key.html:14
msgid "Encrypt your submission."
msgstr ""
msgstr "Yí àfisílẹ̀ rẹ padà fún odù ààbò."
#: source_templates/why-journalist-key.html:16
msgid ""
Expand All @@ -1305,19 +1354,28 @@ msgid ""
"(with .asc at the end), you can just copy and paste that. (don't include "
"the .asc!)"
msgstr ""
"O máa ní láti dá kọ́kọ́rọ́ náà mọ̀ (èyí ni a pè ní \"Ìdánimọ̀ Òǹlò\" tàbí "
"UID). Nítorí pé orúkọ fáìlì kọ́kọ́rọ́ gbogboògbò jẹ́ ìtẹ̀kà kọ́kọ́rọ́ náà "
"(pẹ̀lú .asc ní ẹ̀yin rẹ), o leè gbé ẹ̀dà ìyẹn kọ sílẹ̀. (máà fi "
"<odù>.asc</odù> náà kún un!)"
#: source_templates/why-journalist-key.html:17
msgid ""
"On all systems, open the Terminal and use this gpg command: gpg "
msgstr ""
"Ní oríi gbogbo ẹ̀rọ, ṣí Terminal kí o lo àṣẹ gpg yìí: <odù>gpg --agbaṣẹ́ẹ̀jẹ́"
#: source_templates/why-journalist-key.html:20
msgid ""
"Upload your encrypted submission. It will have the same filename as the "
"unencrypted file, with .gpg at the end (e.g. "
"roswell_photos.pdf.gpg)"
msgstr ""
"Ṣàgbésí àfisílẹ̀ tí odùu rẹ̀ ti yí padà fún ààbò. Yóò ní orúkọ fáìlì kan náà "
"bíi fáìlì tí a kò yí odùu rẹ̀ padà fún ààbò, pẹ̀lú .gpg ní ẹ̀yìn (fún àpẹẹrẹ "
"<odù>àwòránan_roswell.pdf.gpg</odù>)"
#: source_templates/why-journalist-key.html:23
msgid ""
Expand All @@ -1326,7 +1384,11 @@ msgid ""
"--sign or -s flag) as this will reveal your GPG"
" identity to us."
msgstr ""
"<lágbára>Olobó:</lágbára> Bí o bá fẹ́ wà ní ipò àìlórúkọ, <lágbára>o kò "
"gbọdọ̀ </lágbára> lo GPG láti fi ọwọ́ bọ fáìlì náà tí o yí odùu rẹ̀ padà fún "
"ààbò (pẹ̀lú <odù>--fi ọwọ́ bọ</odù> tàbí <odù>-s</odù> àsíá) nítorí èyí yóò "
"fi ìdánimọ̀ GPG rẹ hàn wá."
#: source_templates/why-journalist-key.html:25
msgid "Back to submission page"
msgstr ""
msgstr "Padà sí ojú-ìwé asàfisílẹ̀"
0 comments on commit 570f297
Please sign in to comment.